WAECYorubaLitireso Yoruba2010
WAEC Yoruba Practice Question
medium
Question:
Ojó kan soşo òjò a máa borí òdá. Láipé Ajéwolá gbàgbé pé igbà kan wà rí tí Tóórera iyàwó òun jé àgàn ti ó ń fowó osùn nu ògiri gbígbeę, tí ó n , ń rómo léyìn adię, tí ó b puru sékún, tí àwon ń fojoojúmó sèráhùn omo. Nígbà tí ó yá omo wá pò lóodè rè, òrò rè gbogbo si dayò. Ó ti kúrò nínú o-lóńje-nilé-fi-túlààsi-gbààwè. Kò máa rù hangogo bí alágęemọ. Kò sì máa mì tíétíé bí olókůnrùn mó. Ó kúrò nínú à ń mu hàntúrú, à ń ya ojúlé ààfáà àti adáhunse kiri. Adùn sì wá gbèyin ewúro fún un Kónsónánti àfàfàséfètèpè ni--