WAECYorubaAkoonu Itan2010

WAEC Yoruba Practice Question

medium

Question:

ÈDĖ: AKÀYÉ Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won. Ori yeye ní mògún, tàişe ló po. Idògbé omo Mèmúnà ará İlórò, sèsè ti ibi işé dé ní iròlé ojó yií. Ó jókòo'sí ita láti retí Jókòótadé omo àbúro bàbá rè, tí ó rán ní àkàrà, èyí tí yóò fi je èko. Jéjéniwà ni àbúrò bàbá idògbé. Àti pínníşín ni ó ti gba Idògbé móra, tí ó si fi sí enu ikósé mékániki nigbà tí ó pé omo odún métàlá. İdògbé já fáfá lénu ikósé, ki í pa ibi isé je, tègàn ni hèe. Omọ tó şeé mú yagàn ni. Ní ojó burúkú èşù gbomi mu yií, jijòkòó tí Idògbé jòkòó sí ita pèlú aşo işé re ti o dotí kojá ààlà, ni ó sokùnfà kíkó tí àwon olópàá kó o mó àwọn elégiri tí ó sosé ní àdúgbò keji. Kí a tó şéjú pé, İdogbé ti bá ara rè ní àtimolé olópàá. Ta ni Idògbé rán nísé?